Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 89

1

ORIN DAFIDI 89:15

Yoruba Bible

YCE

Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ó mọ ìhó ayọ̀ nnì, àwọn tí ń rìn ninu ìmọ́lẹ̀ ojurere rẹ, OLUWA

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 89:15

2

ORIN DAFIDI 89:14

Yoruba Bible

YCE

Òdodo ati ẹ̀tọ́ ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ; ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ati òtítọ́ ń lọ ṣiwaju rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 89:14

3

ORIN DAFIDI 89:1

Yoruba Bible

YCE

OLUWA, n óo máa kọrin ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ títí lae; n óo máa fi ẹnu mi kéde òtítọ́ rẹ láti ìran dé ìran.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 89:1

4

ORIN DAFIDI 89:8

Yoruba Bible

YCE

OLUWA, Ọlọrun àwọn ọmọ ogun, ta ló lágbára bíi rẹ? OLUWA, òtítọ́ rẹ yí ọ ká.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 89:8

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest