Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 82

1

ORIN DAFIDI 82:6

Yoruba Bible

YCE

Mo ní, “oriṣa ni yín, gbogbo yín ni ọmọ Ọ̀gá Ògo.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 82:6

2

ORIN DAFIDI 82:3

Yoruba Bible

YCE

Ẹ ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn mẹ̀kúnnù ati àwọn ọmọ aláìníbaba; ẹ sì máa ṣe ẹ̀tọ́ fún àwọn tí ojú ń pọ́n ati àwọn talaka.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 82:3

3

ORIN DAFIDI 82:4

Yoruba Bible

YCE

Ẹ gba talaka ati aláìní sílẹ̀, ẹ gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú.”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 82:4

4

ORIN DAFIDI 82:8

Yoruba Bible

YCE

Dìde, Ọlọrun, ṣe ìdájọ́ ayé, nítorí tìrẹ ni gbogbo orílẹ̀-èdè!

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 82:8

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest