Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 74

1

ORIN DAFIDI 74:16

Yoruba Bible

YCE

Tìrẹ ni ọ̀sán, tìrẹ náà sì ni òru, ìwọ ni o gbé òṣùpá ati oòrùn ró.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 74:16

2

ORIN DAFIDI 74:12

Yoruba Bible

YCE

Ọlọrun, ìwọ ṣá ni ọba wa láti ìbẹ̀rẹ̀ wá; ìwọ ni o máa ń gbà wá là láàrin gbogbo orílẹ̀-èdè.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 74:12

3

ORIN DAFIDI 74:17

Yoruba Bible

YCE

Ìwọ ni o pa gbogbo ààlà ilẹ̀ ayé; ìwọ ni o dá ìgbà òjò ati ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 74:17

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest