Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 68

1

ORIN DAFIDI 68:19

Yoruba Bible

YCE

Ìyìn ni fún OLUWA, Ọlọrun ìgbàlà wa, tí ń bá wa gbé ẹrù wa lojoojumọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 68:19

2

ORIN DAFIDI 68:5

Yoruba Bible

YCE

Baba àwọn aláìníbaba ati olùgbèjà àwọn opó ni Ọlọrun, ní ibùgbé rẹ̀ mímọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 68:5

3

ORIN DAFIDI 68:6

Yoruba Bible

YCE

Ọlọrun, olùpèsè ibùjókòó fún àlejò tí ó nìkan wà; ẹni tí ó kó àwọn ẹlẹ́wọ̀n jáde sinu ìdẹ̀ra, ṣugbọn ó sì fi àwọn ọlọ̀tẹ̀ sílẹ̀ ninu ilẹ̀ gbígbẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 68:6

4

ORIN DAFIDI 68:20

Yoruba Bible

YCE

Ọlọrun tí ń gbani là ni Ọlọrun wa; OLUWA Ọlọrun ni ń yọni lọ́wọ́ ikú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 68:20

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ORIN DAFIDI 68

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò