Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 65

1

ORIN DAFIDI 65:4

Yoruba Bible

YCE

Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí o yàn, tí o mú wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, láti máa gbé inú àgbàlá rẹ. Àwọn ire inú ilé rẹ yóo tẹ́ wa lọ́rùn, àní, àwọn ire inú tẹmpili mímọ́ rẹ!

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 65:4

2

ORIN DAFIDI 65:11

Yoruba Bible

YCE

O mú kí ìkórè oko pọ̀ yanturu ní òpin ọdún; gbogbo ipa ọ̀nà rẹ sì kún fún ọpọlọpọ ìkórè oko.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 65:11

3

ORIN DAFIDI 65:5

Yoruba Bible

YCE

Iṣẹ́ òdodo tí ó bani lẹ́rù ni o fi dá wa lóhùn, Ọlọrun olùgbàlà wa. Ìwọ ni gbogbo àwọn tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé gbẹ́kẹ̀lé, ati àwọn tí wọn wà lórí omi òkun ní ọ̀nà jíjìn réré.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 65:5

4

ORIN DAFIDI 65:3

Yoruba Bible

YCE

nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Nígbà tí ẹ̀ṣẹ̀ wa bá borí wa, ìwọ a máa dáríjì wá.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 65:3

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ORIN DAFIDI 65

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest