1
ORIN DAFIDI 51:10
Yoruba Bible
YCE
Dá ọkàn mímọ́ sí inú mi, Ọlọrun, kí o sì fi ẹ̀mí ọ̀tun ati ẹ̀mí ìṣòótọ́ sí mi lọ́kàn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 51:10
2
ORIN DAFIDI 51:12
Dá ayọ̀ ìgbàlà rẹ pada fún mi, kí o sì fi ẹ̀mí àtiṣe ìfẹ́ rẹ gbé mi ró.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 51:12
3
ORIN DAFIDI 51:11
Má ta mí nù kúrò lọ́dọ̀ rẹ, má sì gba Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ lọ́wọ́ mi.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 51:11
4
ORIN DAFIDI 51:17
Ẹbọ tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ ìwọ Ọlọrun ni ẹ̀mí ìròbìnújẹ́, ọkàn ìròbìnújẹ́ ati ìrònúpìwàdà ni ìwọ kì yóo gàn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 51:17
5
ORIN DAFIDI 51:1-2
Ṣàánú mi, Ọlọrun, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀; nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ pa ẹ̀ṣẹ̀ mi rẹ́. Wẹ̀ mí mọ́ kúrò ninu àìdára mi, kí o sì wẹ̀ mí kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ mi!
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 51:1-2
6
ORIN DAFIDI 51:7
Fi ewé hisopu fọ̀ mí, n óo sì mọ́; wẹ̀ mí, n óo sì funfun ju ẹ̀gbọ̀n òwú lọ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 51:7
7
ORIN DAFIDI 51:4
Ìwọ nìkan, àní, ìwọ nìkan ṣoṣo ni mo ṣẹ̀, tí mo ṣe ohun tí ó burú lójú rẹ, kí ẹjọ́ rẹ lè tọ́ nígbà tí o bá ń dájọ́, kí ọkàn rẹ lè mọ́ nígbà tí o bá ń ṣe ìdájọ́.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 51:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò