1
ORIN DAFIDI 49:20
Yoruba Bible
YCE
Eniyan kò lè máa gbé inú ọlá rẹ̀ títí ayé; bí ẹranko tíí kú, ni òun náà óo ku.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 49:20
2
ORIN DAFIDI 49:15
Ṣugbọn Ọlọrun yóo ra ẹ̀mí mi pada lọ́wọ́ ikú nítorí pé yóo gbà mí.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 49:15
3
ORIN DAFIDI 49:16-17
Má ba ara jẹ́ bí ẹnìkan bá di olówó, tí ọrọ̀ rẹ̀ ń pọ̀ sí i. Nítorí pé ní ọjọ́ tí ó bá kú, kò ní mú ohunkohun lọ́wọ́ lọ; dúkìá rẹ̀ kò sì ní bá a wọ ibojì.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 49:16-17