Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 16

1

ORIN DAFIDI 16:11

Yoruba Bible

YCE

O ti fi ọ̀nà ìyè hàn mí; ayọ̀ kíkún ń bẹ ní iwájú rẹ, ìgbádùn àìlópin sì ń bẹ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 16:11

2

ORIN DAFIDI 16:8

Yoruba Bible

YCE

Mò ń wo OLUWA ní iwájú mi nígbà gbogbo, nítorí pé Ọlọrun dúró tì mí, ẹsẹ̀ mi kò ní yẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 16:8

3

ORIN DAFIDI 16:5

Yoruba Bible

YCE

OLUWA, ìwọ ni ìpín mi, ìwọ ni mo yàn; ìwọ ni ò ń jẹ́ kí ọ̀ràn mi fìdí múlẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 16:5

4

ORIN DAFIDI 16:7

Yoruba Bible

YCE

Èmi óo máa yin OLUWA, ẹni tí ó ń fún mi ní òye; ọkàn mi ó sì máa tọ́ mi sọ́nà ní òròòru.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 16:7

5

ORIN DAFIDI 16:6

Yoruba Bible

YCE

Ìpín tí ó bọ́ sí mi lọ́wọ́ dára pupọ; ogún rere ni ogún ti mo jẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 16:6

6

ORIN DAFIDI 16:1

Yoruba Bible

YCE

Pa mí mọ́ Ọlọrun, nítorí ìwọ ni mo sá di.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 16:1

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ORIN DAFIDI 16

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò