Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 147

1

ORIN DAFIDI 147:3

Yoruba Bible

YCE

Ó ń tu àwọn tí ọkàn wọn bàjẹ́ ninu, ó sì ń dí ọgbẹ́ wọn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 147:3

2

ORIN DAFIDI 147:11

Yoruba Bible

YCE

Ṣugbọn inú OLUWA dùn sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, àwọn tí ó ní ìrètí ninu ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 147:11

3

ORIN DAFIDI 147:5

Yoruba Bible

YCE

OLUWA wa tóbi, ó sì lágbára pupọ òye rẹ̀ kò ní ìwọ̀n.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 147:5

4

ORIN DAFIDI 147:4

Yoruba Bible

YCE

Òun ló mọ iye àwọn ìràwọ̀, òun ló sì fún gbogbo wọn lórúkọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 147:4

5

ORIN DAFIDI 147:6

Yoruba Bible

YCE

OLUWA ní ń gbé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ró, òun ni ó sì ń sọ àwọn eniyan burúkú di ilẹ̀ẹ́lẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 147:6

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò