Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 142

1

ORIN DAFIDI 142:5

Yoruba Bible

YCE

Mo ké pè ọ́, OLUWA, mo ní, “Ìwọ ni ààbò mi, ìwọ ni ìpín mi lórí ilẹ̀ alààyè.”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 142:5

2

ORIN DAFIDI 142:7

Yoruba Bible

YCE

Yọ mí kúrò ninu ìhámọ́, kí n lè yin orúkọ rẹ lógo. Àwọn olódodo yóo yí mi ká, nítorí ọpọlọpọ oore tí o óo ṣe fún mi.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 142:7

3

ORIN DAFIDI 142:3

Yoruba Bible

YCE

Nígbà tí ọkàn mi rẹ̀wẹ̀sì, ó mọ ọ̀nà tí mo lè gbà. Wọ́n ti dẹ tàkúté sílẹ̀ fún mi ní ọ̀nà tí mò ń rìn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 142:3

4

ORIN DAFIDI 142:1

Yoruba Bible

YCE

Mo ké pe OLUWA, mo gbé ohùn ẹ̀bẹ̀ sókè sí i.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 142:1

5

ORIN DAFIDI 142:6

Yoruba Bible

YCE

Gbọ́ igbe mi; nítorí wọ́n ti rẹ̀ mí sílẹ̀ patapata. Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi, nítorí pé wọ́n lágbára jù mí lọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 142:6

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò