Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 115

1

ORIN DAFIDI 115:1

Yoruba Bible

YCE

Ògo kì í ṣe fún wa, OLUWA, Kì í ṣe fún wa, orúkọ rẹ nìkan ṣoṣo ni kí á yìn lógo, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, ati nítorí òtítọ́ rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 115:1

2

ORIN DAFIDI 115:14

Yoruba Bible

YCE

OLUWA yóo jẹ́ kí ẹ máa bí sí i, àtẹ̀yin àtàwọn ọmọ yín.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 115:14

3

ORIN DAFIDI 115:11

Yoruba Bible

YCE

Ẹ̀yin tí ẹ bẹ̀rù OLUWA, ẹ gbẹ́kẹ̀lé e, òun ni olùrànlọ́wọ́ ati aláàbò yín.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 115:11

4

ORIN DAFIDI 115:15

Yoruba Bible

YCE

Kí OLUWA tí ó dá ọ̀run ati ayé bukun yín!

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 115:15

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò