1
ORIN DAFIDI 113:3
Yoruba Bible
YCE
Láti ìlà oòrùn títí dé ìwọ̀ oòrùn, kí á máa yin orúkọ OLUWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 113:3
2
ORIN DAFIDI 113:9
Ó sọ àgàn di ọlọ́mọ, ó sọ ọ́ di abiyamọ onínúdídùn. Ẹ máa yin OLUWA.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 113:9
3
ORIN DAFIDI 113:7
Ó gbé talaka dìde láti inú erùpẹ̀, ó sì gbé aláìní sókè láti orí eérú
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 113:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò