Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 10

1

ORIN DAFIDI 10:17-18

Yoruba Bible

YCE

OLUWA, o óo gbọ́ igbe àwọn tí a nilára; o óo mú wọn lọ́kàn le, o óo sì dẹ etí sílẹ̀ sí igbe wọn kí o lè ṣe ẹ̀tọ́ fún àwọn aláìníbaba ati àwọn ẹni tí à ń pọ́n lójú, kí ọmọ eniyan, erùpẹ̀ lásánlàsàn, má lè dẹ́rù bani mọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 10:17-18

2

ORIN DAFIDI 10:14

Yoruba Bible

YCE

Ṣugbọn ìwọ Ọlọrun rí gbogbo nǹkan, nítòótọ́, o kíyèsí ìṣòro ati ìyà, kí o baà lè fi ọwọ́ ara rẹ gbẹ̀san; nítorí ìwọ ni àwọn aláìṣẹ̀ gbẹ́kẹ̀lé, ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ àwọn aláìníbaba.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 10:14

3

ORIN DAFIDI 10:1

Yoruba Bible

YCE

Kí ló dé tí o fi jìnnà réré, OLUWA, tí o sì fara pamọ́ ní ìgbà ìpọ́njú?

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 10:1

4

ORIN DAFIDI 10:12

Yoruba Bible

YCE

Dìde, OLUWA; Ọlọrun, wá nǹkankan ṣe sí i; má sì gbàgbé àwọn tí a nilára.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 10:12

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ORIN DAFIDI 10

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò