Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ÌWÉ ÒWE 9

1

ÌWÉ ÒWE 9:10

Yoruba Bible

YCE

Ìbẹ̀rù OLUWA ni ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọgbọ́n, ìmọ̀ Ẹni Mímọ́ sì ni làákàyè.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 9:10

2

ÌWÉ ÒWE 9:8

Yoruba Bible

YCE

Má ṣe bá oníyẹ̀yẹ́ eniyan wí, kí ó má baà kórìíra rẹ, bá ọlọ́gbọ́n wí, yóo sì fẹ́ràn rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 9:8

3

ÌWÉ ÒWE 9:9

Yoruba Bible

YCE

Kọ́ ọlọ́gbọ́n, yóo tún gbọ́n sí i, kọ́ olódodo, yóo sì tún ní ìmọ̀ kún ìmọ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 9:9

4

ÌWÉ ÒWE 9:11

Yoruba Bible

YCE

Nípasẹ̀ mi ẹ̀mí rẹ yóo gùn. Ọpọlọpọ ọdún ni o óo sì lò lórí ilẹ̀ alààyè.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 9:11

5

ÌWÉ ÒWE 9:7

Yoruba Bible

YCE

Ẹni tí ń tọ́ oníyẹ̀yẹ́ eniyan sọ́nà fẹ́ kan àbùkù, ẹni tí ń bá ìkà eniyan wí ń wá ìfarapa fún ara rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 9:7

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ÌWÉ ÒWE 9

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò