Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ÌWÉ ÒWE 23

1

ÌWÉ ÒWE 23:24

Yoruba Bible

YCE

Baba olódodo ọmọ yóo láyọ̀ pupọ, inú ẹni tí ó bí ọlọ́gbọ́n ọmọ yóo dùn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 23:24

2

ÌWÉ ÒWE 23:4

Yoruba Bible

YCE

Má ṣe làálàá àṣejù láti kó ọrọ̀ jọ, fi ọgbọ́n sẹ́ ara rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 23:4

3

ÌWÉ ÒWE 23:18

Yoruba Bible

YCE

Dájúdájú, ọjọ́ ọ̀la rẹ yóo dára, ìrètí rẹ náà kò sì ní já sí òfo.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 23:18

4

ÌWÉ ÒWE 23:17

Yoruba Bible

YCE

Má ṣe ìlara àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, ṣugbọn máa bẹ̀rù OLUWA lọ́jọ́ gbogbo.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 23:17

5

ÌWÉ ÒWE 23:13

Yoruba Bible

YCE

Bá ọmọde wí; bí o bá fi pàṣán nà án, kò ní kú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 23:13

6

ÌWÉ ÒWE 23:12

Yoruba Bible

YCE

Fi ọkàn rẹ sí ẹ̀kọ́, kí o sì tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ ìmọ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 23:12

7

ÌWÉ ÒWE 23:5

Yoruba Bible

YCE

Kí o tó ṣẹ́jú pẹ́, owó rẹ lè ti lọ, ó le gúnyẹ̀ẹ́ kí ó fò, bí ìgbà tí ẹyẹ àṣá bá fò lọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 23:5

8

ÌWÉ ÒWE 23:22

Yoruba Bible

YCE

Gbọ́ ti baba tí ó bí ọ, má sì ṣe pẹ̀gàn ìyá rẹ nígbà tí àgbà bá dé sí i.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 23:22

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ÌWÉ ÒWE 23

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò