Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ÌWÉ ÒWE 14

1

ÌWÉ ÒWE 14:12

Yoruba Bible

YCE

Ọ̀nà kan wà tí ó dàbí ẹni pé ó tọ́ lójú eniyan, ṣugbọn òpin rẹ̀, ikú ni.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 14:12

2

ÌWÉ ÒWE 14:30

Yoruba Bible

YCE

Ìbàlẹ̀ ọkàn a máa mú kí ara dá ṣáṣá, ṣugbọn ìlara a máa dá egbò sinu eegun.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 14:30

3

ÌWÉ ÒWE 14:29

Yoruba Bible

YCE

Ẹni tí kì í báá yára bínú lóye lọpọlọpọ, ṣugbọn onínúfùfù ń fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 14:29

4

ÌWÉ ÒWE 14:1

Yoruba Bible

YCE

Ọlọ́gbọ́n obinrin a máa kọ́ ilé rẹ̀, ṣugbọn òmùgọ̀ a máa fi ọwọ́ ara rẹ̀ tú tirẹ̀ palẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 14:1

5

ÌWÉ ÒWE 14:26

Yoruba Bible

YCE

Ninu ìbẹ̀rù OLUWA ni igbẹkẹle tí ó dájú wà, níbẹ̀ ni ààbò wà fún àwọn ọmọ ẹni.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 14:26

6

ÌWÉ ÒWE 14:27

Yoruba Bible

YCE

Ìbẹ̀rù OLUWA ni orísun ìyè, òun níí mú ká yẹra fún tàkúté ikú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 14:27

7

ÌWÉ ÒWE 14:16

Yoruba Bible

YCE

Ọlọ́gbọ́n a máa ṣọ́ra, a sì máa sá fún ibi, ṣugbọn òmùgọ̀ kì í rọra ṣe, kì í sì í bìkítà.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 14:16

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ÌWÉ ÒWE 14

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò