1
LEFITIKU 20:13
Yoruba Bible
YCE
Bí ọkunrin kan bá bá ọkunrin ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ lòpọ̀ bí a ti ń bá obinrin lòpọ̀, àwọn mejeeji ti ṣe ohun ìríra; pípa ni kí wọ́n pa wọ́n, ẹ̀jẹ̀ wọn yóo wà lórí ara wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí LEFITIKU 20:13
2
LEFITIKU 20:7
Nítorí náà, ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì jẹ́ mímọ́, nítorí pé, èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.
Ṣàwárí LEFITIKU 20:7
3
LEFITIKU 20:26
Ẹ níláti jẹ́ mímọ́ fún mi, nítorí pé, mímọ́ ni èmi OLUWA, mo sì ti yà yín sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn eniyan kí ẹ lè máa jẹ́ tèmi.
Ṣàwárí LEFITIKU 20:26
4
LEFITIKU 20:8
Ẹ máa ṣàkíyèsí àwọn ìlànà mi, kí ẹ sì máa tẹ̀lé wọn. Èmi ni OLUWA tí ó sọ yín di mímọ́.
Ṣàwárí LEFITIKU 20:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò