1
JEREMAYA 30:17
Yoruba Bible
YCE
N óo fun yín ní ìlera, n óo sì wo àwọn ọgbẹ́ yín sàn, èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀. Nítorí wọ́n ti pè yín ní ‘Ẹni ìtanù, Sioni tí ẹnikẹ́ni kò bìkítà fún.’ ”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JEREMAYA 30:17
2
JEREMAYA 30:19
Orin ọpẹ́ yóo máa ti ibẹ̀ jáde wá, a óo sì máa gbọ́ ohùn àwọn tí ń ṣe àríyá pẹlu. N óo bukun wọn, wọn óo di pupọ, n óo sọ wọ́n di ẹni iyì, wọn kò sì ní jẹ́ eniyan yẹpẹrẹ.
Ṣàwárí JEREMAYA 30:19
3
JEREMAYA 30:22
Ẹ óo jẹ́ eniyan mi, n óo sì jẹ́ Ọlọrun yín.”
Ṣàwárí JEREMAYA 30:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò