1
ẸKISODU 37:1-2
Yoruba Bible
YCE
Besaleli fi igi akasia àpótí ẹ̀rí náà, gígùn rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ meji ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ kan ààbọ̀, ó sì ga ní igbọnwọ kan ààbọ̀. Ó yọ́ wúrà bò ó ninu ati lóde, ó sì tún fi wúrà ṣe ìgbátí rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ẸKISODU 37:1-2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò