Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10

1

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:10

Yoruba Bible

YCE

Ẹni tí kò bá pọ́n àáké rẹ̀ kí ó mú, yóo lo agbára pupọ bí ó bá fẹ́ lò ó, ṣugbọn ọgbọ́n a máa ranni lọ́wọ́ láti ṣe àṣeyọrí.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:10

2

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:4

Yoruba Bible

YCE

Bí aláṣẹ bá ń bínú sí ọ, má ṣe torí rẹ̀ kúrò ní ìdí iṣẹ́ rẹ, ìtẹríba lè mú kí wọn dárí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó bá tóbi jini.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:4

3

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:1

Yoruba Bible

YCE

Bí òkú eṣinṣin ṣe lè ba òórùn turari jẹ́; bẹ́ẹ̀ ni ìwà òmùgọ̀ kékeré lè ba ọgbọ́n ńlá ati iyì jẹ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:1

4

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:12

Yoruba Bible

YCE

Ọ̀rọ̀ ẹnu ọlọ́gbọ́n a máa bu iyì kún un, ṣugbọn ẹnu òmùgọ̀ ni yóo pa á.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:12

5

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:8

Yoruba Bible

YCE

Ẹni tí ó gbẹ́ kòtò ni yóo jìn sinu rẹ̀, ẹni tí ó bá já ọgbà wọlé ni ejò yóo bùjẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:8

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò