1
AMOSI 5:24
Yoruba Bible
YCE
Ṣugbọn ẹ jẹ́ kí òtítọ́ máa ṣàn bí omi, kí òdodo sì máa ṣàn bí odò tí kò lè gbẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AMOSI 5:24
2
AMOSI 5:14
Ire ni kí ẹ máa wá, kì í ṣe ibi kí ẹ lè wà láàyè; nígbà náà ni OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun yóo wà pẹlu yín, bí ẹ ti jẹ́wọ́ rẹ̀.
Ṣàwárí AMOSI 5:14
3
AMOSI 5:15
Ẹ kórìíra ibi, kí ẹ sì fẹ́ ire, ẹ jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo gbilẹ̀ lẹ́nu ibodè yín; bóyá OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun yóo ṣàánú fún àwọn ọmọ ilé Josẹfu yòókù.
Ṣàwárí AMOSI 5:15
4
AMOSI 5:4
OLUWA ń sọ fún ilé Israẹli pé: “Ẹ wá mi, kí ẹ sì yè
Ṣàwárí AMOSI 5:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò