1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 24:16
Yoruba Bible
YCE
Ìdí nìyí tí mo fi ń sa ipá mi kí ọkàn mi lè jẹ́ mi lẹ́rìí pé inú mi mọ́ sí Ọlọrun ati eniyan nígbà gbogbo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 24:16
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 24:25
Nígbà tí Paulu bẹ̀rẹ̀ sí sọ tirẹ̀ nípa ìwà rere, ìkóra-ẹni-níjàánu, ati ìdájọ́ tí ń bọ̀, ẹ̀rù ba Fẹliksi. Ó bá sọ fún Paulu pé, “Ó tó gẹ́ẹ́ lónìí. Máa lọ. Nígbà tí mo bá ráyè n óo tún ranṣẹ pè ọ́.”
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 24:25
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò