1
ÀWỌN ỌBA KEJI 19:19
Yoruba Bible
YCE
Nisinsinyii OLUWA Ọlọrun wa, jọ̀wọ́ gbà wá lọ́wọ́ Asiria kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé lè mọ̀ pé ìwọ OLUWA nìkan ni ỌLỌRUN.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KEJI 19:19
2
ÀWỌN ỌBA KEJI 19:15
Ó gbadura pé, “OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí ń gbé láàrin àwọn Kerubu, ìwọ nìkan ni Ọlọrun tí ń jọba lórí gbogbo ilẹ̀ ayé, ìwọ ni o dá ayé ati ọ̀run.
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KEJI 19:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò