1
ÀWỌN ỌBA KINNI 8:56
Yoruba Bible
YCE
“Ìyìn ni fún OLUWA, tí ó fún àwọn eniyan rẹ̀ ní ìsinmi gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀. Ó ti mú gbogbo ìlérí rere rẹ̀ tí ó ṣe láti ẹnu Mose, iranṣẹ rẹ̀, ṣẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KINNI 8:56
2
ÀWỌN ỌBA KINNI 8:23
Ó bẹ̀rẹ̀ sí gbadura, ó ní, “OLUWA Ọlọrun Israẹli, kò sí Ọlọrun kan tí ó dàbí rẹ̀ lókè ọ̀run tabi ní ayé yìí, tíí máa pa majẹmu rẹ̀ mọ́, tíí sì máa fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ hàn sí àwọn iranṣẹ rẹ̀, tí ń fi tọkàntọkàn gbọ́ràn sí i lẹ́nu.
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KINNI 8:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò