1
ÀWỌN ỌBA KINNI 14:8
Yoruba Bible
YCE
Mo gba ìjọba lọ́wọ́ ìdílé Dafidi, mo sì fún ọ, o kò ṣe bíi Dafidi, iranṣẹ mi, tí ó pa òfin mi mọ́, tí ó sìn mí tọkàntọkàn, tí ó sì ṣe kìkì ohun tí ó dára lójú mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KINNI 14:8
2
ÀWỌN ỌBA KINNI 14:9
Ṣugbọn o ti dá ọpọlọpọ ẹ̀ṣẹ̀ burúkú ju ti àwọn tí wọ́n jọba ṣáájú rẹ lọ. O yá ère, o sì dá oniruuru oriṣa láti máa sìn, o mú mi bínú, o sì ti pada lẹ́yìn mi.
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KINNI 14:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò