1
ÀWỌN ỌBA KINNI 11:4
Yoruba Bible
YCE
Nígbà tí Solomoni di àgbàlagbà, àwọn iyawo rẹ̀ mú kí ọkàn rẹ̀ ṣí kúrò lọ́dọ̀ OLUWA, ó ń bọ àwọn oriṣa àjèjì, kò sì ṣe olóòótọ́ sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀ mọ́, bíi Dafidi, baba rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KINNI 11:4
2
ÀWỌN ỌBA KINNI 11:9
Inú bí OLUWA sí Solomoni, nítorí pé, ọkàn rẹ̀ ti yipada kúrò lọ́dọ̀ OLUWA Ọlọrun Israẹli tí ó fara hàn án nígbà meji
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KINNI 11:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò