1
KRONIKA KINNI 4:10
Yoruba Bible
YCE
Jabesi gbadura sí Ọlọrun Israẹli pé, “Ọlọrun jọ̀wọ́ bukun mi, sì jẹ́ kí ilẹ̀ ìní mi pọ̀ sí i. Wà pẹlu mi, pa mí mọ́ kúrò ninu ewu, má jẹ́ kí jamba ṣe mí!” Ọlọrun sì ṣe ohun tí ó fẹ́ fún un.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KRONIKA KINNI 4:10
2
KRONIKA KINNI 4:9
Ọkunrin kan, tí à ń pè ní Jabesi, jẹ́ eniyan pataki ju àwọn arakunrin rẹ̀ lọ. Ìyá rẹ̀ sọ ọ́ ní orúkọ yìí nítorí ìrora pupọ tí ó ní nígbà tí ó bí i.
Ṣàwárí KRONIKA KINNI 4:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò