← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Owe 12

Awon owe
Ọjọ́ Mòkanlé lọgbọ̀n
Ètò yìí yóò fàyè gba o láti máa ń ka orí kọ̀ọ̀kan tí Ìwé àwon Òwe lójoojúmó. Ìwé àwon Òwe kún pèlú ọgbọ́n tó sì wà láàyè láti ìran dé ìran, àti yóò máa ṣamọ̀nà rẹ jalè ipa ònà Òdodo.

Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (March)
Ọjọ́ Mòkanlé lọgbọ̀n
Apa keta ti onipin mejila, ètò yìí wà láti darí àwọn egbé tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lápapọ̀ ní ọjọ́ 365. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí le bá Bíbélì Olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogun iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹ̀lú orí Bíbélì láti inú Májẹ̀mú àtijọ́ àti Majẹmu titun, pẹ̀lú Ìwé Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá keta ní àwọn Iwé Nomba, Iwe Owe, Romu, ati Heberu.