← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Iṣe Apo 27:25

Èmi Mímọ́ Wá - Ìrìn Àjò Nínú Ìwé Ìṣe àwọn Aposteli - Pẹ̀lú Lumo
7 Awọn ọjọ
Ṣàwárí agbára àti wíwàà ti Èmi Mímọ́ nípa kika ètò ayínipadà yìí. Ó wá pẹ̀lú fídíò tí LUMO Lórí ìwé Iṣẹ́ àwọn Aposteli, yóò mú imo rẹ jìnlẹ̀ nípa ẹni tí Èmi Mímọ́ jẹ́, àti bí o ṣé ń ṣiṣẹ́ nínú àti nípasẹ̀ àwọn onígbàgbọ́ nígbà yẹn àti ní ìsinsìyìí. Gbáradì láti rí bí agbára rẹ̀ ṣe máa ṣiṣẹ́ láìlópin nínú àti nípasẹ̀ ayé rẹ bí oò ṣe tíì ri rí.