← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Iṣe Apo 17:30

Olódùmarè Tòótọ́
5 Awọn ọjọ
Olódùmarè túmọ̀ sí, "Ẹni tí odù Rẹ̀ kì í rè." Ó jẹ́ orúkọ Yorùbá fún Ẹni Gíga Jùlọ: tí kò ní lópin, tí ó tó dá wa tí ó jẹ́ ayérayé. Ìfọkànsìn ọjọ́ márùn-ún yìí ń tọpasẹ̀ orúkọ yìí dé ọ̀dọ̀ Ẹni tí ó ti sí tòótọ́, ó fihàn bí Ọlọ́run Kristẹni nìkan ṣe bá àpèjúwe yìí mu. Láti Ẹlẹ́dàá, sí Jesu gẹ́gẹ́ bí Ẹlẹ́dàá àti Ètùtù, títí dé Ẹ̀mí Mímọ́ tí ń fi ìyè fúnni, tí ń jí òkú dìde: rí i pé Baba, Ọmọ, àti Ẹ̀mí jẹ́ Olódùmarè tòótọ́ ní ìdọ́gba àti ayérayé: Ọlọ́run kan, Ẹni mẹ́ta.