← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú I. Kor 9:25

Ìdàgbàsókè Ẹ̀mí
5 Awọn ọjọ
Ìdàgbàsókè ẹ̀mí jẹ́ ìlànà tí a fi ń dàgbà nínú ìrìnàjò Kristẹni wa lẹ́yìn ìbí tuntun. Kò jẹ́ ohun tí ń ṣẹlẹ̀ láìlérò; ó nílò ìpinnu, ìtara, ìfaramo, àti ìdíṣe. Nínú ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí, a máa wo àwọn ìpinnu tó tọ́, ìtara fún ohun Ọlọ́run, ìfaramo láti tẹ̀lé ọ̀nà tí a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé, àti ìdíṣe tó jẹ́ kókó fún ìlọsíwájú. Ìdàgbàsókè ẹ̀mí jẹ́ ìmúlò tí ń mu wa sún mọ́ Kristi, kí a sì dà bí àwòrán Rẹ ní gbogbo ohun tí a ṣe.