ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 2:4

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 2:4 YCE

Gbogbo wọn bá kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí sọ oríṣìíríṣìí èdè mìíràn gẹ́gẹ́ bí Ẹ̀mí ti fi fún wọn láti máa sọ.