Filp 1:3-4
Filp 1:3-4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Mo dupẹ lọwọ Ọlọrun mi fun gbogbo iranti nyin ti mo nṣe, Nigbagbogbo ninu gbogbo adura mi fun nyin li emi nfi ayọ̀ bẹ̀bẹ
Pín
Kà Filp 1Filp 1:3-4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Mo dupẹ lọwọ Ọlọrun mi fun gbogbo iranti nyin ti mo nṣe, Nigbagbogbo ninu gbogbo adura mi fun nyin li emi nfi ayọ̀ bẹ̀bẹ
Pín
Kà Filp 1Filp 1:3-4 Yoruba Bible (YCE)
Nígbà gbogbo tí mo bá ranti yín ni mò ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun mi. Nígbà gbogbo ni mò ń gbadura fún gbogbo yín pẹlu ayọ̀ ninu ọkàn mi.
Pín
Kà Filp 1