Jeremiah 39:17-18

Jeremiah 39:17-18 BMYO

Ṣùgbọ́n, Èmi yóò gbà ọ́ lọ́jọ́ náà ni OLúWA wí. A kò ní fi ọ́ lé ọwọ́ àwọn tí o bẹ̀rù. Èmi yóò gbà ọ́ là; o kò ní ṣubú láti ipa idà; ṣùgbọ́n ìwọ yóò sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ, nítorí pé ìwọ ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú mi, ni OLúWA wí.’ ”