Isaiah 25:1

Isaiah 25:1 BMYO

OLúWA, ìwọ ni Ọlọ́run mi; èmi yóò gbé ọ ga èmi ó sì fi ìyìn fún orúkọ rẹ nítorí nínú òtítọ́ aláìlẹ́gbẹ́ o ti ṣe ohun ńlá, àwọn ohun tí o ti gbèrò o rẹ̀ lọ́jọ́ pípẹ́.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Isaiah 25:1

Isaiah 25:1 - OLúWA, ìwọ ni Ọlọ́run mi;
èmi yóò gbé ọ ga èmi ó sì
fi ìyìn fún orúkọ rẹ
nítorí nínú òtítọ́ aláìlẹ́gbẹ́
o ti ṣe ohun ńlá,
àwọn ohun tí o ti gbèrò o rẹ̀ lọ́jọ́ pípẹ́.Isaiah 25:1 - OLúWA, ìwọ ni Ọlọ́run mi;

àwọn ohun tí o ti gbèrò o rẹ̀ lọ́jọ́ pípẹ́.