Gẹnẹsisi 16:13

Gẹnẹsisi 16:13 BMYO

Ó sì pe orúkọ OLúWA tí o bá sọ̀rọ̀ ní, “Ìwọ ni Ọlọ́run tí ó rí mi,” nítorí tí ó wí pé, “Mo ti ri ẹni tí ó rí mi báyìí.”