Gẹnẹsisi 11:9

Gẹnẹsisi 11:9 BMYO

Ìdí èyí ni a fi pè é ní Babeli nítorí ní ibẹ̀ ni OLúWA ti da èdè gbogbo ayé rú. OLúWA tí sì tú àwọn ènìyàn ká sí gbogbo orí ilẹ̀ ayé.