Ìṣe àwọn Aposteli 27:22

Ìṣe àwọn Aposteli 27:22 BMYO

Ǹjẹ́ nísinsin yìí mó gbà yín níyànjú, kí ẹ tújúká; nítorí kí yóò sí òfò ẹ̀mí nínú yín, bí kò ṣe ti ọkọ̀.