ÌWÉ ÒWE 11:28

ÌWÉ ÒWE 11:28 YCE

Ẹni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ rẹ̀ yóo rẹ̀ dànù bí òdòdó, ṣugbọn olódodo yóo rú bí ewé tútù.