Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 96

1

Saamu 96:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí títóbi ní OLúWA ẹni tí ìyìn tọ́ sí; òun ní o yẹ kí a bẹ̀rù ju gbogbo òrìṣà lọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 96:4

2

Saamu 96:2

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹ kọrin sí OLúWA, yin orúkọ rẹ̀ ẹ sọ ti ìgbàlà rẹ̀ ní ọjọ́ dé ọjọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 96:2

3

Saamu 96:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹ kọrin tuntun sí OLúWA, ẹ kọrin sí OLúWA gbogbo ayé.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 96:1

4

Saamu 96:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹ sọ ti ògo rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè àti iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrín gbogbo ènìyàn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 96:3

5

Saamu 96:9

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹ máa sin OLúWA nínú ẹwà ìwà mímọ́ rẹ̀; ẹ wárìrì níwájú rẹ̀ gbogbo ayé.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 96:9

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò