Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 141

1

Saamu 141:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Fi ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ ẹnu mi, OLúWA: kí o sì máa pa ìlẹ̀kùn ètè mi mọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 141:3

2

Saamu 141:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Má ṣe jẹ́ kí ọkàn mi fà sí ohun tí ń ṣe ibi, láti máa bá àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ búburú má sì ṣe jẹ́ kí èmi jẹ àdídùn wọn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 141:4

3

Saamu 141:1-2

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA, èmi ké pè ọ́; yára wá sí ọ̀dọ̀ mi. Gbọ́ ohùn mi, nígbà tí mo bá ń ké pè ọ́. Jẹ́ kí àdúrà mi ó wá sí iwájú rẹ bí ẹbọ tùràrí àti ìgbé ọwọ́ mi si òkè rí bí ẹbọ àṣálẹ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 141:1-2

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 141

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò