Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Òwe 31

1

Òwe 31:30

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ojú dáradára a máa tan ni, ẹwà sì jẹ́ asán nítorí obìnrin tí ó bẹ̀rù OLúWA yẹ kí ó gba oríyìn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 31:30

2

Òwe 31:25-26

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Agbára àti ọlá ni ó wò ọ́ láṣọ ó le fi ọjọ́ iwájú rẹ́rìn-ín. A sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ọgbọ́n ìkọ́ni òtítọ́ sì ń bẹ létè e rẹ̀

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 31:25-26

3

Òwe 31:20

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

O la ọwọ́ rẹ̀ sí àwọn tálákà ó sì na ọwọ́ rẹ̀ sí àwọn aláìní.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 31:20

4

Òwe 31:10

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ta ni ó le rí aya oníwà rere? Ó níye lórí ju iyùn lọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 31:10

5

Òwe 31:31

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Sì fún un ní èrè tí ó tọ́ sí i kí o sì jẹ́ kí iṣẹ́ rẹ̀ fún un ní ìyìn ní ẹnu ibodè ìlú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 31:31

6

Òwe 31:28

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Àwọn ọmọ rẹ̀ dìde wọ́n sì pè é ní alábùkún ọkọ rẹ̀ pẹ̀lú ń gbóríyìn fún un.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 31:28

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Òwe 31

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò