Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Eksodu 14

1

Eksodu 14:14

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA yóò jà fún un yín; kí ẹ̀yin kí ó sá à mu sùúrù.”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Eksodu 14:14

2

Eksodu 14:13

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nígbà náà ni Mose sọ fún àwọn ènìyàn náà pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ dúró ṣinṣin kí ẹ sì rí ìdáǹdè tí OLúWA yóò fi fún un yín lónìí, àwọn ará Ejibiti ti ẹ̀yin rí lónìí ni ẹ kò ni tún padà rí wọn mọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Eksodu 14:13

3

Eksodu 14:16

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ṣùgbọ́n, gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè, kí o sì na ọwọ́ rẹ sí orí omi Òkun, kí ó lè pín ní yà kí àwọn ọmọ Israẹli lè la òkun kọjá ni orí ìyàngbẹ ilẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Eksodu 14:16

4

Eksodu 14:31

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nígbà ti àwọn ọmọ Israẹli rí iṣẹ́ ìyanu ńlá ti OLúWA ṣe fún wọn lára àwọn ará Ejibiti, àwọn ènìyàn bẹ̀rù OLúWA, wọ́n sì gba OLúWA àti Mose ìránṣẹ́ rẹ gbọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Eksodu 14:31

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò