Eks 22:22-23
Eks 22:22-23 YBCV
Ẹnyin kò gbọdọ jẹ opó ni ìya, tabi ọmọ alainibaba. Bi iwọ ba jẹ wọn ni ìyakiya, ti nwọn si kigbe pè mi, emi o gbọ́ igbe wọn nitõtọ.