YouVersion 로고
성경묵상동영상
앱 다운로드
언어 선택
검색 아이콘

Gẹnẹsisi 16 - 인기 성경 구절

1

Gẹnẹsisi 16:13

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ó sì pe orúkọ OLúWA tí o bá sọ̀rọ̀ ní, “Ìwọ ni Ọlọ́run tí ó rí mi,” nítorí tí ó wí pé, “Mo ti ri ẹni tí ó rí mi báyìí.”

비교

Gẹnẹsisi 16:13 살펴보기

2

Gẹnẹsisi 16:11

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Angẹli OLúWA náà sì wí fún un pé, “Ìwọ ti lóyún, ìwọ yóò sì bí ọmọkùnrin kan. Ìwọ yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Iṣmaeli, nítorí tí OLúWA ti rí ìpọ́njú rẹ.

비교

Gẹnẹsisi 16:11 살펴보기

3

Gẹnẹsisi 16:12

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Òun yóò jẹ́ oníjàgídíjàgan ènìyàn ọwọ́ rẹ̀ yóò wà lára ènìyàn gbogbo, ọwọ́ ènìyàn gbogbo yóò sì wà lára rẹ̀, yóò sì máa gbé ní ìkanra pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀.”

비교

Gẹnẹsisi 16:12 살펴보기

Gẹnẹsisi 16: 관련 무료 묵상 계획

이전 장
다음 장
YouVersion

매일 하나님과 친밀하게 동행하도록 격려하고 도전하기.

사역

소개

채용 정보

자원 봉사

블로그

기사

유용한 링크

도움

후원

성경 번역본

오디오 성경

성경 언어

오늘의 말씀


디지털 사역

Life.Church
한국어

©2026 Life.Church / YouVersion

개인 정보 취급 정책약관
취약점 공개 프로그램
페이스북트위터인스타그램유튜브핀터레스트