1
Hosea 14:9
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Ta ni ọlọ́gbọ́n? Òun yóò mòye àwọn nǹkan wọ̀nyí. Ta a ní ó mọ̀? Òun yóò ní ìmọ̀ wọn. Títọ́ ni ọ̀nà OLúWA àwọn olódodo si ń rìn nínú wọn, ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́tẹ̀ ni yóò kọsẹ̀ nínú wọn.
ប្រៀបធៀប
រុករក Hosea 14:9
2
Hosea 14:2
Ẹ gba ọ̀rọ̀ OLúWA gbọ́, kí ẹ sì yípadà sí OLúWA. Ẹ sọ fún un pé, “Darí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá kí o sì fi oore-ọ̀fẹ́ gbà wá, kí àwa kí ó lè fi ètè wa sán an fún ọ
រុករក Hosea 14:2
3
Hosea 14:4
“Èmi wo àgàbàgebè wọn sàn, Èmi ó sì fẹ́ràn wọn, lọ́fẹ̀ẹ́, nítorí ìbínú mi ti yípadà kúrò lọ́dọ̀ wọn.
រុករក Hosea 14:4
គេហ៍
ព្រះគម្ពីរ
គម្រោងអាន
វីដេអូ