YouVersion Logo
Search Icon

Saamu 145:3

Saamu 145:3 BMYO

Títóbi ni OLúWA. Òun sì ni ó yẹ láti fi ìyìn fún púpọ̀púpọ̀: kò sí ẹni tí ó lè wọn títóbi rẹ̀.

Video for Saamu 145:3