ORIN DAFIDI 124
124
Ọlọrun Aláàbò Àwọn Eniyan Rẹ̀
1Tí kì í bá ṣe pé OLUWA tí ó wà lẹ́yìn wa,
ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ wí pé,
2“Tí kì í bá ṣe pé OLUWA tí ó wà lẹ́yìn wa
nígbà tí ọmọ aráyé gbógun tì wá,
3wọn ìbá gbé wa mì láàyè,
nígbà tí inú bí wọn sí wa;
4àgbàrá ìbá ti gbá wa lọ,
ìṣàn omi ìbá ti bò wá mọ́lẹ̀;
5ìgbì omi ìbá ti gbé wa mì.”
6Ọpẹ́ ni fún OLUWA,
tí kò fi wá ṣe ẹran ìjẹ fún wọn.
7A ti yọ, bí ẹyẹ tí ó yọ ninu okùn apẹyẹ:
okùn ti já; àwa sì ti yọ.
8Ọ̀dọ̀ OLUWA ni ìrànlọ́wọ́ wa ti wá,
ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé.
Currently Selected:
ORIN DAFIDI 124: YCE
Highlight
Copy
Compare
Share
Want to have your highlights saved across all your devices? Sign up or sign in
Bible Society of Nigeria © 1900/2010
ORIN DAFIDI 124
124
Ọlọrun Aláàbò Àwọn Eniyan Rẹ̀
1Tí kì í bá ṣe pé OLUWA tí ó wà lẹ́yìn wa,
ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ wí pé,
2“Tí kì í bá ṣe pé OLUWA tí ó wà lẹ́yìn wa
nígbà tí ọmọ aráyé gbógun tì wá,
3wọn ìbá gbé wa mì láàyè,
nígbà tí inú bí wọn sí wa;
4àgbàrá ìbá ti gbá wa lọ,
ìṣàn omi ìbá ti bò wá mọ́lẹ̀;
5ìgbì omi ìbá ti gbé wa mì.”
6Ọpẹ́ ni fún OLUWA,
tí kò fi wá ṣe ẹran ìjẹ fún wọn.
7A ti yọ, bí ẹyẹ tí ó yọ ninu okùn apẹyẹ:
okùn ti já; àwa sì ti yọ.
8Ọ̀dọ̀ OLUWA ni ìrànlọ́wọ́ wa ti wá,
ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé.
Currently Selected:
:
Highlight
Copy
Compare
Share
Want to have your highlights saved across all your devices? Sign up or sign in
Bible Society of Nigeria © 1900/2010