ẸKISODU 1:15

ẸKISODU 1:15 BM

Nígbà tí ó yá, ọba Ijipti pe àwọn obinrin Heberu tí wọ́n ń gbẹ̀bí, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Ṣifira ati Pua, ó sọ fún wọn pé
BM: Yoruba Bible
Share