1
Saamu 149:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Nítorí OLúWA ní inú dídùn sí àwọn ènìyàn rẹ̀ ó fi ìgbàlà dé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ládé.
Compare
Explore Saamu 149:4
2
Saamu 149:6
Kí ìyìn Ọlọ́run kí ó wà ní ẹnu wọn àti idà olójú méjì ní ọwọ́ wọn.
Explore Saamu 149:6
3
Saamu 149:1
Ẹ fi ìyìn fún OLúWA. Ẹ kọrin tuntun sí OLúWA. Ẹ yìn ín ní àwùjọ àwọn ènìyàn mímọ́.
Explore Saamu 149:1
Home
Bible
Plans
Videos